![lirikku.id](/inc/logo.png)
Lirik Lagu Congress musicfactory – Mímó Ni Òdó Àgùtan
By: Admin | Artist: C congress musicfactory | Published: 2024-06-07T22:39:43:00+07:00
![Lirik Lagu Congress musicfactory – Mímó Ni Òdó Àgùtan](https://i0.wp.com/file.laponta.id/img/uploads/lirik-lagu-congress musicfactory-mímó-ni-òdó-àgùtan.png)
mímó ni òdó àgùtan
[akorin}
mimo, mimo
mimo l’odo agutan
oluwa alagbara
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o tun nbo wa
[akorin]
mimo, mimo
mimo l’odo agutan
oluwa alagbara
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o tun nbo wa
[ẹsẹ 1]
gbogbo eda f’ogo fun o
gbogbo okan wa bukun f’oruko re
ede, eya ati awon orile ede
eniyan mimo nkorin iyin re
[akorin]
mimo, mimo
mimo l’odo agutan
oluwa alagbara
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o tun nbo wa
[ẹsẹ 2]
a teriba nibi mimo re
a gbowo s’oke a juba re
oluwa eyin nikan l’owo yi ye
iwo nikan ni gbogbo iyin ye
gbogbo iyin
[akorin]
mimo, mimo
mimo l’odo agutan
oluwa alagbara
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o tun nbo wa
[ipari]
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa to tun nbo waaaa
Saksikan Video Lirik Lagu Congress musicfactory – Mímó Ni Òdó Àgùtan Berikut ini..
Lirik lagu lainnya:
- lirik lagu miguel trafficante – ko bi drugi nego ja
- lirik lagu c stocks – new slaves freestyle
- lirik lagu pony pony run run – walking on a line (lifelike remix)
- lirik lagu rikard “skizz” bizzi – ingenting förändras (utom du)
- lirik lagu dj screw – i got 5 on it freestyle
- lirik lagu berry bonkers – tired n throwed
- lirik lagu michael schulte – wide awake
- lirik lagu the hollies – long cool woman (in a black dress)
- lirik lagu aceyalone & slippers – 200,000 years
- lirik lagu pikeno e menor – carimba que é top